AHAN by Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo Lyrics

Looking for the Yoruba lyrics to “AHAN” by Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo from the album Queen of Sheba (2022)? More than 106 people have already found the lyrics of the song for karaoke, the notes of the melody to the song, the official video and clip of the song “AHAN”.

AHAN yo Lyrics [Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo]
AHAN Yoruba Lyrics Album Queen of Sheba

Quote from the song “AHAN” by Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo

Kossi, kpashan kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi, kpashan kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan, kossi Shèkèshèkè kan

LyricsWord.com

Can you finish lyrics of the song “AHAN” based on this quote?

If you can't then the lyrics will be below ...AHAN lyrics [Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo]

Ibrahim Maalouf & Angélique Kidjo: AHAN Lyrics

Perfect Lyrics of the Song “AHAN” Released in 2022

[Favorite Song Lyrics: song “AHAN” with perfect lyrics for karaoke]

Kossi, kpashan kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi, kpashan kan, kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan, kossi Shèkèshèkè kan

E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Eyin nin Ọba, enin Oba Jerusalemu
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Ni waju yin, Emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun

E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Eyin ti èsso m’kpé moji omi orisun yin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun

Shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
Ninou owo wo lè n’mou ida yin o?
Shugbon M’bo l’owa lara yin oooo
Shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
Kabi èssè yin to n’sare lo si ogun
Shugbon te ni ailopin Agbara léri eniyan

E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Eyin nin Ọba, enin Oba Jerusalemu
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Ni waju yin, Emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Emi ti èsso m’kpé moji omi orisun yin